Tags
Language
Tags
April 2024
Su Mo Tu We Th Fr Sa
31 1 2 3 4 5 6
7 8 9 10 11 12 13
14 15 16 17 18 19 20
21 22 23 24 25 26 27
28 29 30 1 2 3 4

AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language

Posted By: Sigha
AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language

AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language
Video: .mp4 (1280x720, 30 fps(r)) | Audio: aac, 48000 Hz, 2ch | Size: 1.23 GB
Genre: eLearning Video | Duration: 71 lectures (6 hour, 28 mins) | Language: English

Ẹ kọ Software Testing Ati Automation, Test Analyst, QA Tester, Software Test Engineer ati bẹ bẹ lọ ni ede Yoruba

What you'll learn

Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation
A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications
A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database
A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications
A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver
A o kọ lati lo Exploratory Testing
A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database
A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard
A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database
A o kọ Data Migration Testing
A o kọ lati le Report Bugs Tabi Defects
A o kọ End To End Testing
A o kọ Regression Testing
A o kọ lati lo MSSQL Server Database fun Extract Transform Load (ETL Testing) ati Database Testing
A o kọ lati le Create Test Script Template pẹlu Microsoft Excel fun Desktop, Mobile ati Web Applications
A o kọ lati Gain Working Experience As a Primary Tester at bẹ bẹ lọ

Course content
11 sections • 71 lectures • 6h 28m total length

Requirements

Computer - Windows OS
Passion

Description

Ẹ kabọ si course ton jẹ Kọ Software Testing Ati Automation Pẹlu (Real-Life Projects).

Lakọkọ ẹ jẹ ki a ni lo kan wipe course yi ma jẹ hands-on training tutorial (itumo nin pe 90% practical ati 10% theories). Kiko ni mi mo.

Ninu Course yi ẹ ma learn step by step Manual and Automation Software Testing (Functional) ti a ma lo WinAutomation, Selenium WebDriver 3 ati iMacros browser addons fun automating the Functional part of Web Applications pẹlu over 20+ real life projects.

Software Testing Manual ati Automation jẹ most important skills lati le test front-end ati backend Web Application, Desktop Applications ati Mobile Apps. Paapa ju li lo iMacros ati Selenium WebDriver 3 fun GUI automation, Software Testing Automation je popular larin large community.

Course yi structured si ọ nọ pupọọ:

Awọn ẹkọ yi pisi video screencast ati guide, Homework wa ni be ti a ma se, Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation, A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications, A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database, A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications, A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver, A o kọ lati lo Extract Transform Load (ETL Testing), MS Excel, Notepad++, Test Script, ati Java Code Templates, A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database, A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard, A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database, A o kọ Data Migration Testing, A o kọ lati le Report Bugs tabi Defects ati bẹ bẹ lọ.

Who this course is for:

Ẹkọ yi wa fu ẹni ti o ba fẹ di :-
Test Analyst
Software Quality Assurance Tester
Mobile Tester
Web Application Tester
Software Test Automation Engineer
Ati Ẹni ti o ba fẹ revise lo ri Testing Skills

AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language



For More Courses Visit & Bookmark Your Preferred Language Blog
From Here: English - Français - Italiano - Deutsch - Español - Português - Polski - Türkçe - Русский